Ẹ fọ ẹja, edé àti irú, ẹ dàápọ̀ pẹ̀lú ẹran bibọ, ẹja gbígbẹ, iyọ̀, irú, iyọ̀ igbàlódé àti omi sinú ikòkò kan. Ẹ gbe ka iná fún sisè. Bi ẹ ti nse lọ, ẹ da epo-pupa sinú ikòkò keji. Ẹ yọ epo díẹ̀, ki ẹ da àpọ̀n si lati yọ àpnọ̀ yi, bi ó ba ti gbónọ́ díẹ̀, ẹ da gbogbo èlò ọbẹ̀ inú ikòkò kini ni gbí-gbónọ́ sinú ikòkò keji ti epo àti àpọ̀n wa. Ẹ ro pọ, ẹ yi iná rẹ silẹ̀ díẹ, ki ẹ ro titi yio fi jiná. Ti ọbẹ̀ na bá ki jù, ẹ bu omi gbi-gbónọ́ díẹ si titi yio ri bi ẹ ṣe fẹ́.
-
-
Se Ẹja gbígbẹ, Pọ̀nmọ́, Ṣàki, àti èlo miràn pẹ̀lú omi sinú ikòkò kan – Cook dried fish, tripe and other ingredients with water in one pot. Courtesy: @theyorubablog
-
-
Ẹ yọ epo – Dissolve palm oil. Courtesy: @theyorubablog
-
-
Àpọ̀n – Wild mango seed powder. Courtesy: @theyorubablog
-
-
Da àpọ̀n sinú epo-pupa yiyọ́ – Add wild mango seed powder into the dissolved palm oil. Courtesy: @theyorubablog
-
-
Da èlò ọbẹ̀ inú ikòkò kini ni gbí-gbónọ́ sinú ikòkò keji ti epo àti àpọ̀n wa – Add the meat & stock into the warm palm oil with the wild mango seed powder. Courtesy: @theyorubablog
-
-
Ro titi yio fi jiná – Stir till it is cooked. Courtesy: @theyorubablog
ENGLISH TRANSLATION Continue reading →
Originally posted 2015-03-20 10:15:26. Republished by Blog Post Promoter