Yorùbá ma npa ìtàn lati fi ṣe à ri kọ́gbọ́n tàbi fún ìkìlọ̀. Ẹ ṣọ́ra lati fi ìbẹ̀rù àti ojo bẹ̀rẹ̀ ọdún nitori a ma a géni kúrú. Lára ẹ̀kọ́ ti a lè ri fi kọ́ ọgbọ́n ni ìtàn ti a ka yi ni wi pé, onikálukú ni Ọlọrun fún ni ẹ̀bùn àti àyè ti rẹ̀ ni ayé. Ohun ti ó dára ni ìṣọ̀kan, ẹ̀kọ́ wa lati kọ́ lára bi ẹranko ti ó ni agbára ṣe mba ara wọ́n gbé, ó dára ki a gba ìkìlọ̀ àgbà tàbi ẹni ti ó bá ṣe nkan ṣáájú àti pé ìjayà tàbi ìbẹ̀rù lè gé ènìà kúrú bi o ti sọ ọmọ Ẹkùn di Ológbò.
Ẹ ka ìtàn yi ni èdè Gẹ̀ẹ́sì ni ojú ewé Yorùbá lóri ayélujára ti a kọ ni ọdún Ẹgbàálémẹ́rìndínlógún, oṣù kẹta, ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n.
ENGLISH TRANSLATION
In Yoruba Culture stories are told to learn from example or to warn. Be careful on stepping into the New Year with fear, because fear reduces one’s potential. Some of the lessons that can be Continue reading
Originally posted 2018-01-19 00:47:17. Republished by Blog Post Promoter