A rọ ẹnikẹni ti ó ni ìfẹ́ èdè àti àṣà Yorùbá (pàtàki ọmọ ilé-iwé giga ti ó nkọ ẹ̀kọ́ èdè Yorùbá) ki ó kọ àròkọ fún “theyorubablog” lóri ayélujára. Àròkọ ti èrò bá kà jù tàbi ti wọn ni ìfẹ́ rẹ jù yio gba ẹ̀bùn ti a o ṣe ni ọdọọdún. Àròkọ na a gbọ́dọ̀ ni àwọn ohun wọnyi: Continue reading
Originally posted 2015-03-03 09:30:41. Republished by Blog Post Promoter