Aṣọ Yorùbá kò pé, lai si Gèlè. Bi Yorùbá bá wọ aṣọ ìbílẹ̀ fún òde ojoojúmọ́ tàbi fún ayẹyẹ, wọn ni lati wé gèlè ki imúra lè pé. Fún ji jade ojoojúmọ́, a lè lo ipèlé aṣọ àdirẹ àti àwọn aṣọ igbàlódé lati fi wé gèlè, ṣùgbọ́n fún òde gidi, gèlè igbàlódé tàbi Aṣọ Òfì ti wọn npe ni Aṣọ Òkè ni Yorùbá ma nwe. Eleyi jẹ ki imúra Yorùbá gbayì ni gbogbo àgbáyé. Ẹ ṣe àyẹ̀wò wi wé gèlè ni ojú iwé yi.
ENGLISH TRANSLATION
Yoruba traditional outfit is incomplete without the head tie. Yoruba traditional outfit either casual or occasional wear is expected to be complimented with head tie. For casual wear, part of the fabric such as Tie & Dye Fabric or other cotton fabric are often used as head tie, but for special occasion, modern scarf or Traditional woven clothes known as “Aso-Oke” are used as head tie. This has made Yoruba traditional outfits unique all over the world. Check out on this page further details on how to tie head scarf or head tie in the video.
Originally posted 2015-07-07 19:36:07. Republished by Blog Post Promoter