Yorùbá ni “Ọmọdé ò jobì, àgbà ò jẹ oye”, òwe yi bá àwọn òbí ti ó kọ ọmọ sílẹ̀, ìyá ti ó ta ọmọ, bàbá ti ó sá fi ọmọ sílẹ̀ àti àwọn ti o fi ìyà jẹ ọmọ, irú ọ̀pọ̀lọpọ̀ òbí bayi ni òṣì má ta pa. Kò sí àyè fún ọmọ irú àwọn bayi lati mọ wọn lójú nítorí wọn o si nílé lati ṣe ojuṣe wọn gẹ́gẹ́bí òbi ati lati kọ́ ọmọ aláìgbọràn. Irú orin bayi ló tọ́ sí irú òbí bẹ̃:
MP3 Below:
Download: Ise obi fun omo – Parental responsibilities
Íya tó kọ̀ ọ̀mọ̀ rẹ sílẹẹ̀
Oṣí yo tà yà na paá
Bába tó kọ̀ ọ̀mọ rẹ́ silẹ̀
Oṣí yo tà bà nà paá
Ìyà tò fiyà jẹ ọmọ́ rẹ
Bàbà tò fiyà jẹ ọmọ́ rẹ
Íya tó kọ̀ ọ̀mọ̀ rẹ sílẹẹ̀
Oṣí yo tà yà na paá
Bába tó kọ̀ ọ̀mọ rẹ́ silẹ̀
Oṣí yo tà bà nà paá
ENGLISH TRANSLATION
According to the “Yoruba Proverbs” by Oyekan Owomoyela’s translation, “The youth does not eat kola nuts; the elder does not win the chieftaincy title” meaning (If you do not cultivate others, even those lesser than yourself, then you cannot expect any consideration from them). This is apt to describe the consequence for a mother that sells her child, a father that abandon his children and those abusing their children. Many children has no privilege of seeing their parents when they are young let alone disobey or refuse correction, hence such parents would be the ones to suffer poverty in the end. The song below is for parents that have abandoned their role:
Mother that abandoned her child
Will suffer poverty in the end
Father that abandoned his child
Will suffer poverty in the end
Mother that abuses her child
Father that abuses his child
Mother that abandoned her child
Will suffer poverty in the end
Father that abandoned his child
Will suffer poverty in the end
Originally posted 2013-07-26 20:30:36. Republished by Blog Post Promoter
Yorubas are noted to be a kinship oriented society that embodied responsibility and virtue. When any parents decided to abandon responsibilities especially in the family, it could be devastating to the entire family, since we are economically and socially interwoven. Children tend to mirror their parents and internerlized them, but when such parents are absent in the lives of the children , then the vacuum is created for bad self object for the children to internerlize. This is a serious episode that requires great attention, and for a Yoruba person it requires our concern as “OMOLUABI”. ‘Ti ile ba san ni awo lanwo’, more need to be done as we should revive our cultural responsibilities.