Yorùbá ka ìpanu si ohun ti anjẹ lati mu inu duro pataki ni arin ounje aro ati ale. A le ka si ounje osan.
Traditionally, Yoruba people regard snacks as stop-gap chewable, particularly between breakfast and dinner. These are also often regarded as lunch. The most popular traditional Yoruba snacks are below:
Àádùn | Mixed Roasted Corn flour paste |
Dòdò Ìkirè | Ìkirè Fried Plantain |
Àkàrà Òṣú | Fried Beans paste from Oṣu |
Kókóró | Groundnut snack |
Ìpékeré | Plantain Chips |
Ẹpa | Groundnut |
Gúgúrú | Popcorn |
Gúgúrú ati ẹpa | Popcorn and Groundnut |
Bọọli | Roasted Plantain |
Bọọli ati ẹpa | Roasted Plantain and Groundnut |
Bọọli ati epo pupa | Roasted Plantain & Palm Oil |
Dùndú | Yam Chips |
Iṣu sisun | Roasted Yam |
Àgbàdo Sise | Boiled Corn |
Àgbàdo Sisun | Roasted Corn |
Àgbọn | Coconut |
Àgbàdo sisun ati àgbọn | Roasted Corn & Coconut |
Gàrí wíwà/mímu | Soaked coarsed casava flour |
Originally posted 2013-02-22 18:41:13. Republished by Blog Post Promoter