“Ọmọ ẹni kì í burú títí, ká fi fún ẹkùn pajẹ ” – ìdájọ́ fún ìyá àti ọkọ-ìyá Daniel Pelka: “One’s child cannot be bad to the extent of throwing him/her to the Leopard to devour”, judgement for Daniel Pelka’s mother and step-father
Gẹgẹ bi Òwe Yorùba,́ “Ọmọ ẹni kì í burú títí, ká fi fún ẹkùn pajẹ”. Òwe yi bá ìṣẹ̀lẹ̀ burúkú ti ó ṣẹlẹ̀ si Daniel Pelka mu. Kò tọ́ ki ìyá Daniel Pelka ti o yẹ ki ó dáàbò bo ọmọ fi ìyà jẹ ọmọ ọdún mẹrin yi dé ojú ikú. Ọmọ kékeré yi jẹ̀ ìyà kú lọ́wọ́ ìyá àti ọkọ rẹ.
Kini ọmọ ọdún mẹrin lè ṣe lati gbèjà ara rẹ lọ́wọ́ òbí burúkú? Kòsí ohun ti ọmọdé lè ṣe, ṣugbọn Ìjọba fa obìnrin àti ọkùnrin burúkú yi lọ si Ilé-Ẹjo. Wọ́n gba ìdájọ́ èyí ti wọn ni lati lo ọgbọn ọdún ó kéré jù. Ẹ wo ìròyìn yi:
ENGLISH LANGUAGE
According to Yoruba proverb that said “One’s child cannot be bad to the extent of throwing him/her to the Leopard to devour”. This proverb is applicable to the evil incidence that happened to Daniel Pelka. It is not appropriate for Daniel Pelka’s mother that ought to have protected her son to punish the four year old to death. This young child suffered to death in the hands of his mother and step-father.
What can a four year old do to protect him/herself in the hands of wicked parent? There is nothing a young child can do, but the Government dragged this wicked woman and man to Court. They got the judgement they deserved of at least thirty (30) years imprisonment. Read the news below:
http://www.bbc.co.uk/