Kò di igbà ti enia bá ni owó rẹpẹtẹ ki ó tó sọ ọmọ rẹ ni “Ọlá” nitori Yorùbá ka ipò giga, ọmọ, ilera, orúkọ rere si “Ọlá”. Ibi ti “Ọlá” wà ninú orúkọ Yorùbá, a lè lo “Adé; Ibi; Olú; Ọmọ; Oyè” dipò. Fún àpẹrẹ, “Ọláyẹmi; Adéyẹmi; Ibiyẹmi; Olúyẹmi; Ọmọyẹmi àti Oyèyẹmi”.
ENGLISH TRANSLATION
It is not until a person has so much money before naming a child “Ola which connotes Wealth”, because Yoruba regard, high position in the society, children, good health, good name etc as “Wealth”. Wherever “Ola” appears in a name, it can also be replaced with “Ade – Crown; Ibi – Birth; Omo – Child; Oye – Chieftaincy”. For example “Olayemi; Adeyemi; Ibiyemi; Oluyemi; Omoyemi and Oyeyemi”.
B TO N |
|
|
Yoruba Names | Short Form | English meaning |
Bọ̀bọ́lá | Bọ̀bọ́ | Met wealth |
Bọ́ládalẹ́ | Bọ́lá | Remain with wealth till night |
Bọlajoko | Bọla | Seat with wealth |
Bọ́lánlé | Bọ́lá | Met wealth at home |
Bọ́látitó | Bọ́lá | How great the wealth |
Dámilọ́lá | Dámi | Prosper me |
Dáramọ́lá | Dára | Beautiful with wealth |
Dúródọlá | Dúró | Wait for wealth |
Dúrótọlá | Dúró | Wait with wealth |
Ẹniọlá | Ẹni | Wealthy/Prominent Personality |
Fadéjimi | Jimi | Leave the crown with me |
Faramádé | Mádé | Associate with the crown |
Faramọ́lá | Fara | Associate with wealth |
Fẹ̀hintọlá | Tọlá | Lean back on wealth |
Fọlábi | Fọ́la | Came at the time of convenience |
Fọlájimi | Jimi | Leave the wealth with me |
Fọláhàn | Fọlá | Show off wealth |
Fọlákẹ́mi | Fọlákẹ́ | Use wealth to pet me |
Fọlámi | Fọlá | Breathing in wealth |
Fọláṣadé | Ṣadé | Use wealth as crown |
Fọláyan | Fọlá | Boastful in wealth |
Fọláyẹmi | Yẹmi | Let wealth suit me |
Fúnmikẹ́/Fúnkẹ́ | Funkẹ | Given to me to pet |
Ibitọ́lá | Ibi | Birth is equal to wealth |
Ikẹ́adé | Ikẹ | Care of the Crown |
Imisiọla | Imisi | The breath of wealth |
Iniọla | Ini | Ownership of wealth |
Iretiọla | Ireti | Expectation of wealth |
Iyiọla | Iyi | The honour of wealth |
Jayéọlá | Jayé | Enjoy wealth |
Jayéọba | Jayé | Enjoy kingship |
Jadesọla | Jade | Come into wealth |
Jokotọla | Joko | Seat in the company of wealth |
Jọ́ládé | Jọ́lá | Let wealth come |
Jọláadé | Jọlá/Adé | Enjoy the wealth of crown |
Jọ́láyẹmi | Jọla/Yẹmi | Let wealth suit me |
Káriọlá | Kári | The wealth got round |
Kayinsọla | Káyin | Drop honey in to wealth |
Kẹ́misọ́lá | Kẹ́mi | Pet me into wealth |
Kọ́lápọ̀ | Kọ́lá | Bring wealth together |
Kọ́láwọlé | Kọ́lá | Bring wealth home |
Mobọ́láji | Bọ́láji | I woke up with wealth |
Monisọ́lá | Moni | There is an addition to my wealth |
Mosúnmọ́lá | Mosún | I got closer to wealth |
Moyọ̀sádé | Moyọ̀ | I rejoice into crown |
Moyọ̀sọ́lá | Moyọ̀ | I rejoice into wealth |
Ninisọ́lá | Nini | Having an addition to wealth |
O TO W
OrúkọYorùbá | Short Form | English meaning of Yoruba Names |
Olútọ́lá | Olú/Tọ́lá | Having God is equal to wealth |
Ọbátẹ́rù | Tẹ́rù | The king is enough to fear |
Ọbáṣúyi | Ṣuyi | The king create honour |
Ọlábimpé | Bimpe | Born complete in wealth |
Ọlábisi | Bisi | Procreated wealth |
Ọlábọ̀dé | Bọ̀dé | Wealth has arrived |
Ọlábọ̀wálé | Wálé | Wealth has returned home |
Ọládàpọ̀ | Dàpọ̀ | Mixture of wealth |
Ọládipọ̀/Ọládipúpọ̀ | Dipọ | Wealth has increased |
Ọládunni | Dunni | Wealth is good to have |
Ọláifẹ | Ifẹ́ | Wealth of love |
Ọláitan/Ọláòtán | Laitan | Unending wealth |
Ọláiyá | Ọlá | Mother’s wealth |
Ọlákunbi | Kunbi | Wealth has added to birth |
Ọlákunmi | Kunmi | Wealth is added to me |
Ọlálekan/Ọlámilekan | Lekan | An addition to my wealth |
Ọlálérè | Lérè | Wealth is profitable |
Ọlálẹyẹ | Lẹyẹ | Wealth has honour |
Ọlamide | Mide | My wealth has come |
Ọlámipọ̀si | Pọ̀si | My wealth has increased |
Olaniran | Niran | Wealth has lineage |
Ọlániyi | Niyi | Wealth is honourable |
Ọlánrewájú/Ọlárewájú | Lanre | Progressive wealth |
Ọláolú | Láolú | God’s wealth |
Ọláoyè | Laoye | Wealth of chieftaincy |
Ọlásanmi | Sanmi | Wealth is good for me |
Ọlásúnkanmi | Súnkànmi/Kànmi | Wealth has moved closer to me |
Ọlátúndé | Túndé | Wealth has returned |
Ọláwálé | Wálé | Wealth has come home |
Ọláwọlé | Wọlé | Wealth has entered home |
Ọláwunmi | Wunmi | I love wealth |
Ọláyẹmi | Yẹmi | Wealth is suits me |
Ọláyinka | Yinka | Surrounded by wealth |
Ọlọ́ládé | Lọ́lá/Lọ́ládé | The weathy one is here |
Olúfúnmilọ́lá | Fúnmi/Fúnlọ́lá | God gave me wealth |
Olúṣọlá | Ṣọlá | God made wealth |
Olúwatómilọ́lá | Tómi | God is enough for me as wealth |
Ọmọlọlá | Lọlá | Child is wealth |
Owólabi | Owó | Given birth to wealth |
Owóẹ̀yẹ | Owó | Honourable Money |
Owoyẹmi | Yẹmi | Money suits me |
Oyèbọ́lá | Oyè/Bọ́lá | Title met wealth |
Oyèdiran | Diran | Title is part of the family |
Oyèyẹmi | Yẹmi | Chieftaincy/Title suits me |
Oyèyinka | Yinka | Surrounded by Titles |
Oyinladé | Ladé | The crown is honey |
Oyindàmọ́lá | Dàmọ́lá | Honey mixed with wealth |
Oyinlọlá | Oyin | Honey is wealth |
Pariọlá | Pari | Completion of wealth |
Ṣijúadé | Ṣiju | Open eyes to see the crown |
Ṣijuwọla | Ṣiju/Wọlá | Be open to wealth |
Simisọ́lá | Simi | Rest in wealth |
Ṣọlápé | Lápé | Complete wealth |
Tẹjúmádé | Tẹjú/Mádé | Focus on the crown |
Tẹjúmọ́lá | Tẹjú/Mọ́lá | Focus on wealth |
Tèmiladé | Tèmi | Mine is the crown |
Tèmilọlá | Tèmi/Lọlá | Mine is wealth |
Tẹ́niọlá | Tẹni | Spread the mat of wealth |
Tinúọlá | Tinú | In the midst of wealth |
Titilọlá | Titi | Continuous wealth |
Tiwaladé | Ladé | Ours is the crown |
Tiwalọla | Tiwa | Ours is the wealth |
Tọ́misọ́lá | Tomi | Teach me into wealth |
Tóyèbi | Tóyè | Rebirth of the title |
Wọnúọlá | Wọnú | Enter into wealth |
Wọnúadé | Wọnú | Enter into the crown |
Originally posted 2014-07-04 23:41:51. Republished by Blog Post Promoter
I could not resist commentіng. Well written!