Ọbabinrin Elizabeth Keji, pé aadọrun ọdún láyé ni ọjọ́ kọkànlélógún, oṣù kẹrin ọdún Ẹgbàálémẹrindinlólgún. Gbogbo ará ilú àti àwọn Ìjọ Onigbàgbọ́ pé jọ lati ṣe ayẹyẹ à ṣe pọ̀ fún Ọbabinrin ni ọjọ́ Ìsimi, ọjọ́ kejila, oṣù kẹfà ọdún. Eleyi bọ si àsikò ti ọkọ rẹ Philips pé ọgọrundinmarun ọdún.
Lẹhin ti Ọbabinrin Elizabeth keji gun ori oyè ni ọdún mẹtalelọgọta sẹhin, ó bẹ ilú Èkó wò ni ọgọta ọdún sẹhin, nigbati Ilú Èkó jẹ́ Olú-Ilú orilẹ̀ èdè Nigeria ki a tó gba Òminira lábẹ́ Ilú-Ọba ni odun Ẹdẹgbaalelọgọta. A ṣe yi ṣe àmọ́dún o. Ẹ ṣe àyẹ̀wò àwòrán wọnyi.
ENGLISH TRANSLATION
Queen Elizabeth II, was ninety years on 21 April, 2016. People and Churches all over the country came together for Street celebration on Sunday June 12. This day coincided with Prince Philip, Duke of Edinburgh’s ninety-fifth birthday.
After Queen Elizabeth II was crowned about sixty-three years ago (1952), she visited Lagos about sixty years ago in 1956, when Lagos was still the capital of Nigeria before Independence in 1960. Wishing her more years of celebration. Check some pictures of the day’s celebration.
Originally posted 2016-06-14 22:22:27. Republished by Blog Post Promoter