About the Blog

Èdè Yorùbá jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn èdè pàtàkì tí àwọn ẹ̀yà tí o ngbe ní Ìwọ̀-õrun orílẹ̀ èdè Nàíjérìa nsọ.  Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀yà Ìwọ̀-õrun ilẹ̀ aláwọ̀ dúdú títí dé Brazil nsọ àyídà èdè Yorùbá.  Ọmọ Odùduwà ni gbogbo ọmọ Yorùbá lagbaaye.  Ní àsìkò ayélujára yi, ìkọ̀wé èdè Yorùbá lórí ayélujára yio fún gbogbo ọmọ Yorùbá lagbaaye, tóní ìfẹ́ lati gbé àṣà àti èdè Yorùbá lárugẹ kí o ma ba parẹ́ láyè lati jírò.

Ẹ fi ojú sọ́nà lọ́sọ̀sẹ̀ fún ọ̀rọ̀ titun fún àpérò lórí àyè ìkọ̀wé yi.

Ẹjọ̀wọ́ ẹ fi ọ̀rọ̀ àsọyé lati ba Olùkọ̀wé yi sọ̀rọ̀ sílẹ̀.  Bí ẹ bá fẹ́ kí a tẹ ìwé tí ẹ kọ, ẹ fi ìwé ìrántí sílẹ̀.

ENGLISH TRANSLATION

The Yoruba language is one of the major languages spoken in the Western part of Nigeria. Variants of the language are spoken across West Africa, in the United Kingdom and in Brazil. Yoruba people all over the world are generally regarded as children of Oduduwa. The Yoruba Blog will try to stimulate conversation in and about Yoruba.

Look out for new posts every week.

Register if you will like to submit posts on the Yoruba blog.

 

 

 

Share Button