A rọ ẹnikẹni ti ó ni ìfẹ́ èdè àti àṣà Yorùbá (pàtàki ọmọ ilé-iwé giga ti ó nkọ ẹ̀kọ́ èdè Yorùbá) ki ó kọ àròkọ fún “theyorubablog” lóri ayélujára. Àròkọ ti èrò bá kà jù tàbi ti wọn ni ìfẹ́ rẹ jù yio gba ẹ̀bùn ti a o ṣe ni ọdọọdún. Àròkọ na a gbọ́dọ̀ ni àwọn ohun wọnyi:
Àkọ́kọ́, àròkọ ni lati wà nipa: Àṣà, Ìtàn, Àlọ́, Oúnjẹ, Ọdún ìbílẹ̀, Òrìsà ilẹ̀ Yorùbá àti bẹ́ ẹ̀ bẹ́ ẹ̀ lọ
Èkejì, gbogbo àròkọ kò gbọdọ̀ kọjá Ẹgbẹ̀rún ọ̀rọ̀ fún èdè Yorùbá àti itumọ rẹ ni èdè Gẹ̀ẹ́si
Ẹkẹta, dara pọ̀ mọ́ “theyorubablog” lóri ayélujára, ki ẹ si fi àròkọ na a silẹ̀.
Àròkọ gbi gba wọlé yio pari ni Ọgbọ̀n ọjọ́, oṣù keje ọdún Ẹgbãlemẹ̃dogun
Ọrẹ-iyin fún Ipò kini – Ẹdẹgbãjọ Naira, Ipò Keji – Ẹdẹgbãrunlẹgbẹta Naira, Ipò Kẹta – Ẹdẹ̃gbata Naira. Bi ọ̀mì bá wà, àròkọ ti wọn bá kà jù lóri ayélujára ni yio gba ipò kini.
ENGLISH TRANSLATION
The Yoruba Blog is inviting anyone that is passionate about Yoruba language and culture, particularly students of Higher Institutions studying Yoruba (lets go Great Akokites!), to submit articles for publication on the theyorubablog.com as part of the 2015 Annual Yoruba Blog Competition
RULES
Firstly, the ideal article would be about Yoruba culture, folklore, riddles, food, traditional festivals and gods, with original images e.t.c.
Secondly, the article must not be more than one thousand words in both the Yoruba and English Translation.
Thirdly, participants must register with The Yoruba Blog and then submit your article as a contributor.
Entries for this year’s competition close on July 30, 2015.
The submission with the most Facebook likes as of 11:59pm October 1, 2015 wins!
In the event of a tie the most read of the published articles will decide.
PRIZES
1st Prize: N15,000.00
2nd Prize: N7,500.00
3rd Prize: N5,000.00
For questions or difficulty submitting articles email theyorubablog@gmail.com
Yoruba-blog-annual-competition
Originally posted 2015-03-03 09:30:41. Republished by Blog Post Promoter